Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 29:13 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní,“Nítorí pé ẹnu nìkan ni àwọn eniyan wọnyi fi ń súnmọ́ mi,ètè lásán ni wọ́n sì fi ń yìn mí;ṣugbọn ọkàn wọn jìnnà sí mi.Òfin eniyan, tí wọn kọ́ sórí lásán, ni ìbẹ̀rù mi sì jẹ́ fún wọn.

Ka pipe ipin Aisaya 29

Wo Aisaya 29:13 ni o tọ