Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 29:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà n óo tún ṣe ohun ìyanu sí àwọn eniyan wọnyi,ohun ìyanu tí ó jọni lójú.Ọgbọ́n yóo parẹ́ mọ́ àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n ninu,ìmọ̀ràn yóo sì parẹ́ mọ́ àwọn ọ̀mọ̀ràn níkùn.”

Ka pipe ipin Aisaya 29

Wo Aisaya 29:14 ni o tọ