Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Títù 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bákan náà, ni kí ó kọ́ àwọn àgbà obìnrin lẹ́kọ̀ọ́ láti kọ́ bí àátí gbé ìgbé-ayé ẹni-ọ̀wọ̀, wọn kò gbọdọ̀ jẹ́ afọ̀rọ̀-kẹ́lẹ́-ba-tẹni-jẹ́ tàbí olùfẹ́ wáìnì mímú, ṣùgbọ́n wọ́n gbọdọ̀ jẹ́ olùkọ́ ohun rere.

Ka pipe ipin Títù 2

Wo Títù 2:3 ni o tọ