Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Títù 2:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kọ́ àwọn àgbà ọkùnrin lẹ́kọ̀ọ́ láti ní ìrònú àti láti jẹ́ ẹni àpọ́nlé àti ẹni ìwọ̀ntúnwọ̀nsì. Wọn gbọdọ̀ jẹ́ ẹni tí ó jinlẹ̀ nínú ìgbàgbọ́, nínú ìfẹ́ àti nínú ìpamọ́ra.

Ka pipe ipin Títù 2

Wo Títù 2:2 ni o tọ