Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 9:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Jésù sì ti ń rékọjá láti ibẹ̀ lọ, o rí ọkùnrun kan ti à ń pè ní Mátíù, ó jókòó ní ibùdó àwọn agbowó-òde, ó sì wí fún un pé, “Máa tọ̀ mí lẹ́yìn,” Mátíù sì dìde, ó ń tọ̀ ọ́ lẹ́yìn.

Ka pipe ipin Mátíù 9

Wo Mátíù 9:9 ni o tọ