Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 9:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ìjọ ènìyàn rí í ẹnu sì yà wọ́n, wọ́n yin Ọlọ́run lógo, ti ó fi irú agbára báyìí fún ènìyàn.

Ka pipe ipin Mátíù 9

Wo Mátíù 9:8 ni o tọ