Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 9:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ṣe, bí Jésù tí jókòó ti ó ń jẹun nínú ilé Mátíù, sì kíyèsí i, ọ̀pọ̀ àwọn agbowó-òde àti “ẹlẹ́sẹ̀” wá, wọ́n sì bá a jẹun pẹ̀lú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀.

Ka pipe ipin Mátíù 9

Wo Mátíù 9:10 ni o tọ