Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 21:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù wí fún wọn pé, “Lóòótọ́ ni mo wí fún yín, bí ẹ̀yin bá lè ní ìgbàgbọ́ láì síyè méjì, nígbà náà ẹ̀yin yóò lè ṣe irú tí a se sí igi ọ̀pọ̀tọ́, Ẹ̀yin yóò lè sọ fún òkè yìí pé, ‘Yí ipò padà sínú òkun,’ yóò sì ríbẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Mátíù 21

Wo Mátíù 21:21 ni o tọ