Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 21:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí wọ́n ti sún mọ́ Jérúsalẹmu, tí wọ́n dé ìtòòsí ìlú Bẹ́tífágè ní orí òkè Ólífì, Jésù sì rán àwọn ọmọ-ẹ̀yìn méjì,

Ka pipe ipin Mátíù 21

Wo Mátíù 21:1 ni o tọ