Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 13:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Díẹ̀ bọ́ sórí ilẹ̀ orí àpáta, níbi ti kò sí erùpẹ̀ púpọ̀. Àwọn irúgbìn náà sì dàgbà sókè kíákíá, nítorí erùpẹ̀ kò pọ̀ lórí wọn.

Ka pipe ipin Mátíù 13

Wo Mátíù 13:5 ni o tọ