Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 13:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n nígbà tí òòrùn gòkè, oòrùn gbígbóná jó wọn, gbogbo wọ sì rọ, wọ́n kú nítorí wọn kò ni gbòǹgbò.

Ka pipe ipin Mátíù 13

Wo Mátíù 13:6 ni o tọ