Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 9:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí o kọ̀ awọn Ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, o si wí fun wọn pe, “A o fi Ọmọ ènìyàn lé àwọn ènìyàn lọ́wọ́, wọn ó sì pa á, lẹ́yìn ìgbà tí a bá sì pa á tan yóò jíǹde ní ijọ́ kẹta.”

Ka pipe ipin Máàkù 9

Wo Máàkù 9:31 ni o tọ