Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 9:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Jésù ti ń súnmọ́ ọ̀pọ̀ ènìyàn wọ̀nyí ni wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ sí í wò ó pẹ̀lú ìbẹ̀rù, nígbà náà ni wọ́n sáré lọ kí i.

Ka pipe ipin Máàkù 9

Wo Máàkù 9:15 ni o tọ