Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 9:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wí fún wọn pé, “Lóòtọ́ ni mo wí fún un yín àwọn mìíràn wa nínú àwọn tó dúró níhìnín yìí, tí kì yóò tọ́ ikú wò, títi yóò fi rí ìjọba Ọlọ́run tí yóò fi dé pẹ̀lú agbára.”

Ka pipe ipin Máàkù 9

Wo Máàkù 9:1 ni o tọ