Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 8:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítori náà, ó pàsẹ fún àwọn ènìyàn náà láti jókòó lórí ilẹ̀. Ó sì mú odindi búrédì méje náà, ó dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run, ó sì bù wọ́n sí wẹ́wẹ́, ó pín wọ́n fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ láti gbé ka iwájú àwọn ènìyàn, wọ́n sì ṣe bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Máàkù 8

Wo Máàkù 8:6 ni o tọ