Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 8:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí kọ́ wọn, pé, Ọmọ Ènìyàn kò le má sàì jìyà ohun púpọ̀, a ó sì kọ̀ ọ́ sílẹ̀ láti ọwọ́ àwọn àgbààgbà, àwọn olórí àlùfáà àti àwọn olùkọ́-òfin, a ó sì pa á, lẹ́yìn ijọ́ mẹ́ta yóò sì jíǹde.

Ka pipe ipin Máàkù 8

Wo Máàkù 8:31 ni o tọ