Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 2:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó tí wọ ilé Ọlọ́run lọ ni ọjọ́ Ábíátarì olórí àlùfáà, tí ó sì jẹ búrẹ́dì ìfihàn ti kò tọ́ fún un láti jẹ bí kò ṣe fún àwọn àlùfáà, ó sì tún fi fún àwọn tí ń bẹ lọ́dọ̀ rẹ̀.”

Ka pipe ipin Máàkù 2

Wo Máàkù 2:26 ni o tọ