Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 2:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó dá wọn lóhùn pé, “Ẹ̀yín kò tí kà ohun tí Dáfídì ṣe, nígbà tí ó ṣe aláìní, tí ebi sì ń pa á, òun àti àwọn tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ̀?

Ka pipe ipin Máàkù 2

Wo Máàkù 2:25 ni o tọ