Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 12:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìránṣẹ́ kan ṣoṣo ló kù tí Baba olóko kò ì tí ì rán níṣẹ́, èyí ni ọmọ òun tìkárarẹ̀. Níkẹyìn ó ran an sí àwọn àgbẹ̀ náà, pẹ̀lú èrò pé, ‘Wọn yóò bu ọlá fún ọmọ òun.’

Ka pipe ipin Máàkù 12

Wo Máàkù 12:6 ni o tọ