Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 12:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n rí ọmọ baba olóko, wọ́n sọ fún ara wọn pé, ‘Ọmọ rẹ̀ ló ń bọ̀ yìí. Òun ni yóò jogún oko yìí tí baba rẹ̀ bá kú. Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a pa á, lẹ́yìn náà oko náà yóò di tiwa.’

Ka pipe ipin Máàkù 12

Wo Máàkù 12:7 ni o tọ