Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 12:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí àwa kí ó fi fún un, tàbí kí a máa fi fún un?” Ṣùgbọ́n Jésù mọ ìwà àgàbàgebè wọn. Ó sì wí pé, “Èéṣe tí ẹ̀yin fi fi èyí dán mi wo? Ẹ mú owó idẹ kan wá kí n wò ó.”

Ka pipe ipin Máàkù 12

Wo Máàkù 12:15 ni o tọ