Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 12:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí wọn ti dé ọ̀dọ̀ rẹ̀, wọ́n wí pé: “Olùkọ́, àwa mọ̀ pé ìwọ máa ń sọ òtítọ́ tìrẹ láìsí ìbẹ̀rù ẹnikẹ́ni. Ṣùgbọ́n òtítọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ni ìwọ máa ń kọ́ni. Nísinsin yìí, sọ fún wa, ó tọ́ tàbí kò tọ́ láti máa san owó orí fún Késárì?

Ka pipe ipin Máàkù 12

Wo Máàkù 12:14 ni o tọ