Nígbà tí ó sì gbé ojú rẹ̀ sókè sí àwọn ọmọ èyìn rẹ̀, ó ní:“Alábùkún fún ni ẹ̀yin òtòsì,nítorí tiyín ni ìjọba Ọlọ́run.