Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 6:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Alábùkún fún ni ẹ̀yin tí ebi ń panísinsin yìí; nítorí tí ẹ ó yòó.Alábùkún fún ni ẹ̀yin tí ńsọkún nísinsin yìí: nítorí tí ẹ̀yin ó rẹ́rìn-ín.

Ka pipe ipin Lúùkù 6

Wo Lúùkù 6:21 ni o tọ