Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 24:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ṣe, bí wọ́n ti ń bá ara wọn sọ̀rọ̀, tí wọ́n sì ń bá ara wọn jíròrò, Jésù tìkara rẹ̀ súnmọ́ wọn, ó sì ń bá wọn rìn lọ.

Ka pipe ipin Lúùkù 24

Wo Lúùkù 24:15 ni o tọ