Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 10:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ohun gbogbo ni a ti fi fún mi láti ọ̀dọ̀ Baba mi; kò sì sí ẹni tí ó mọ ẹni tí ọmọ jẹ́, bí kò ṣe Baba; àti ẹnikẹ́ni tí ó bá sì wu ọmọ láti fi í hàn fún.”

Ka pipe ipin Lúùkù 10

Wo Lúùkù 10:22 ni o tọ