Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 10:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní wákàtí kan náà Jésù yọ̀ nínú Ẹ̀mí mímọ́ ó sì wí pé, “Mo dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, Baba, Olúwa ọ̀run àti ayé, pé, ìwọ pa nǹkan wọ̀nyí mọ́ kúrò lọ́dọ̀ àwọn ọlọ́gbọ́n àti amòye, ìwọ sì fi wọ́n hàn fún àwọn ọmọ ọwọ́: bẹ́ẹ̀ ni, Baba, bẹ́ẹ̀ ni ó sáà yẹ ní ojú rẹ.

Ka pipe ipin Lúùkù 10

Wo Lúùkù 10:21 ni o tọ