Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kólósè 4:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìkíni láti ọwọ́ èmi Pọ́ọ̀lù. Ẹ máa ránti ìdè mi. Kí oore-ọ̀fẹ́ kí ó wà pẹ̀lú yín. Àmín. A kọ ọ́ láti Rómù lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn ará Kólósè láti ọwọ́ Tíkíkù àti Ónísímù.

Ka pipe ipin Kólósè 4

Wo Kólósè 4:18 ni o tọ