Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kólósè 4:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Épáfúrà, ẹni tí ń ṣe ọ̀kan nínú yín àtiìránṣẹ́ Kírísítì kí í yín. Òun fí ìwàyájà gbàdúrà nígbà gbogbo fún-ún yín, kí ẹ̀yin kí ó lè dúró ní pípé nínú ohun gbogbo nínú ìfẹ́ Ọlọ́run.

Ka pipe ipin Kólósè 4

Wo Kólósè 4:12 ni o tọ