Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kólósè 4:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti Jésù, ẹni tí à ń pè ní Jọsítọ́sì, ẹni tí ń ṣe ti àwọn onílà. Àwọn wọ̀nyí nìkan ni olùbá ṣiṣẹ́ mí fún ìjọba Ọlọ́run, àwọn ẹni tí ó tí já sí ìtùnú fún mi.

Ka pipe ipin Kólósè 4

Wo Kólósè 4:11 ni o tọ