Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 11:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sì fi àgbàlá tí ń bẹ lóde tẹ́ḿpìlì sílẹ̀, má si ṣe wọ̀n ọ́n; nítorí tí a fi fún àwọn aláìkọlà: ìlú mímọ́ náà ni wọn ó sì tẹ̀ mọ́lẹ̀ ní oṣù méjì lé lógójì.

Ka pipe ipin Ìfihàn 11

Wo Ìfihàn 11:2 ni o tọ