Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 11:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì ṣí tẹ́ḿpìlì Ọlọ́run sílẹ̀ ní ọ̀run, a sì ri àpótí májẹ̀mu nínú tẹ́ḿpìlì rẹ̀. Mọ̀nàmọ́ná sì kọ, a sì gbọ́ ohùn, àrá sì sán, ilẹ́ sì mi, yìnyín ńlá sì bọ́.

Ka pipe ipin Ìfihàn 11

Wo Ìfihàn 11:19 ni o tọ