Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 11:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Inú bí àwọn orílẹ̀-èdè, bẹ́ẹ̀ni ìbínú rẹ̀ ti dé,àti àkókò láti dá àwọn òkú lẹ́jọ́,àti láti fi èrè fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ wòlíì,àti àwọn ènìyàn mímọ́, àti àwọn tí o bẹ̀rù orúkọ rẹ̀,àti ẹni kékeré àti ẹni ńlá;àti láti run àwọn tí ń pa ayé run.”

Ka pipe ipin Ìfihàn 11

Wo Ìfihàn 11:18 ni o tọ