Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 10:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mó sì rí ańgẹ́lì mìíràn alágbára ò ń ti ọ̀run sọ̀kalẹ̀ wá, a fi awọsànmà wọ̀ ọ́ ni aṣọ; òṣùmàrè sì ń bẹ ní orí rẹ̀, ojú rẹ̀ sì dàbí òòrùn, àti ẹṣẹ̀ rẹ̀ bí ọ̀wọ́n iná.

Ka pipe ipin Ìfihàn 10

Wo Ìfihàn 10:1 ni o tọ