Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mósè náà yìí tí wọ́n kọ̀, wí pé, ‘Ta ni ó fi jẹ olórí àti onídàájọ́?’ Òun náà ni Ọlọ́run rán lọ láti ọwọ́ ańgẹ́lì, tí ó farahàn án ní ìgbẹ́, láti ṣe olórí àti olùdáǹdè.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:35 ni o tọ