Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní rírí mo ti rí ìpọ́njú àwọn ènìyàn mi tí ń bẹ ni Íjíbítì, mo sì ti gbọ́ ìkérora wọn, mo sì sọ̀kalẹ̀ wá láti gbà wọ́n. Wá nísinsìn yìí, èmi ó sì rán ọ lọ sí ilẹ̀ Íjíbítì.’

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:34 ni o tọ