Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní àkókò náà ni a bí Mósè, ẹni tí ó lẹ́wà púpọ̀, tí wọn sí bọ́ lóṣù mẹ́ta ni ilé baba rẹ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:20 ni o tọ