Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun náà ni ó ṣe àrékekè sí àwọn ìbátan wa. Wọn sì hùwà búburú sí àwọn baba wa, tó bẹ́ẹ̀ tí wọ́n fi já àwọn ọmọ-ọwọ́ wọn kúrò lọ́wọ́ wọn nítorí kí wọn má ṣe yè.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:19 ni o tọ