Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Agbára ńlá ni àwọn àpósítélì sì fi ń jẹ́rìí àjíǹde Jésù Olúwa, Oore-ọ̀fẹ́ púpọ̀ sì wà lórí gbogbo wọn.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:33 ni o tọ