Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìjọ àwọn tí ó gbàgbọ́ sì wà ní ọkàn kan àti inú kan; kò sì sí ẹnìkan tí ó wí pé ohun kan nínú ohun ìní rẹ̀ jẹ́ ti ara rẹ̀; ṣùgbọ́n gbogbo wọn ní ohun gbogbo ní ìsọ̀kan.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:32 ni o tọ