Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àkókó yìí kan náà, ó ń retí pẹ̀lú pé Pọ́ọ̀lù yóò mú owó-ẹ̀yìn wá fún òun, kí òun baà lè dá a sílẹ̀: nítorí náà, a sì máa ránṣẹ́ sì í nígbàkúgbà, a máa bá a sọ̀rọ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:26 ni o tọ