Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn ọjọ́ mélòó kan Fẹ́líkísì pẹ̀lú Dírúsílà ìyàwó rẹ̀ dé, obìrin tí í ṣe Júù. Ó ranṣẹ́ pé Pọ́ọ̀lù, ó sì gbọ́ ọ̀rọ̀ lẹ́nu rẹ̀ nípa ìgbàgbọ́ nínú Kírísítì Jésù.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 24:24 ni o tọ