Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì di ariwo ńlá, nínú àwọn olùkọ́ òfin tí ó wà ni apá tí àwọn Farisí dìde, wọ́n ń jà, wí pé, “Àwa kò rí ohun búburú kan lára ọkùnrin yìí,” wọ́n wí “àwa kò sì mọ̀ nítòótọ́ bí áńgẹ́lì kan tàbí ẹ̀mí kan ń baà sọ̀rọ̀?”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:9 ni o tọ