Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ń ṣe èyí lọ́jọ́ púpọ̀, ṣùgbọ́n nígbà tí inú Pọ́ọ̀lù bàjẹ́, tí ó sì yípadà, ó wí fún ẹ̀mí náà pé, “Mo pàṣẹ fún ọ ní orúkọ Jéṣù Kíríṣítì kí o jáde kúrò lára rẹ̀!” Ó sí jáde ni wákàtí kan náà.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:18 ni o tọ