Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun náà ni ó ń tọ Pọ́ọ̀lù àti àwa lẹ́hìn, ó sì ń kígbe, pé, “Àwọn ọkùnrin wọ̀nyí ni ìránṣẹ Ọlọ́run Ọ̀gá-ògo, tí ń kéde ọ̀nà ìgbàlà fún yin!”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:17 ni o tọ