Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gálátíà 2:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n kàkà bẹ́ẹ̀, nígbà tí wọn rí i pé a tí fi ìyìn rere tí àwọn aláìkọlà le mi lọ́wọ́, bí a tí fi ìyìn rere tí àwọn onílà lé Pétérù lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Gálátíà 2

Wo Gálátíà 2:7 ni o tọ