Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gálátíà 2:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ní ti àwọn tí ó dàbí ẹni pàtàkì—ohunkóhun tí ó wù kì wọn já sí, kò jẹ́ nǹkan kan fún mi; Ọlọ́run kò fi bí ẹnìkẹ́ni se rí se ìdájọ́ rẹ̀—àwọn eniyan yìí kò fi ohunkóhun kún ọ̀rọ̀ mi.

Ka pipe ipin Gálátíà 2

Wo Gálátíà 2:6 ni o tọ