Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 8:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ẹni tí ń sìn nínú pẹpẹ kan tí ó jẹ́ ẹ̀dá àti òjìji ohun tí ń lọ́run. Ìdí abájọ nìyí tí a fi kìlọ̀ fún Mósè nígbà tí ó kọ́ àgọ́: Nítorí ó wí pé, “Kíyèsí kí o ṣe ohun gbogbo gẹ́gẹ́ bí àpẹẹrẹ tí a fihàn ọ lórí òkè.”

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 8

Wo Àwọn Hébérù 8:5 ni o tọ