Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Pétérù 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Agbára rẹ̀ bí Ọlọ́run ti fún wa ní ohun gbogbo tí í ṣe ti ìyè àti ti ìwà-bí-Ọlọ́run, nípa ìmọ̀ ẹni tí ó pè wá nípa Ògo àti ìṣeun rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Pétérù 1

Wo 2 Pétérù 1:3 ni o tọ