Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Pétérù 1:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa èyí tí ó fi àwọn ìlérí rẹ̀ tí ó tóbi púpọ̀ tí ó ṣe iyebíye fún wá: pé nípa ìwọ̀nyí ni kí ẹ̀yin lè di alábàápín nínú àbùdá ti Ọlọ́run, nígbà tí ẹ̀yín bá ti yọ kúrò nínú ìbàjẹ́ tí ó ń bẹ nínú ayé nípa ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́.

Ka pipe ipin 2 Pétérù 1

Wo 2 Pétérù 1:4 ni o tọ